I offer eyele (pigeon) to my Ifa, I'm sure that all good things in life will be fit me. Ase Edumare

Okiti baba ni pekun opopo,
Adifafun Orunmila baba nlore na iku ni opa abo,Ebo lawo ni kose,
Oloni moro naku lopa abo,osi fi jinjin ni kan iku.......
Olodumare yio bawa deru ba ota wa,iku koni pawa ni kekere o,
ASE Edumare
Aku Ose Ifa loni...

Copyright Babaawo Ifaseyi Alabi, phone and whatsapp contact + 2348132625855